| Always | Nígbà gbogbo |
| The doctor advised us to always eat well | Dókítà gbà wá ní ìmọ̀ràn láti máa jẹun dáadáa nígbà gbogbo |
| Never | Láíláí |
| I will never do this again! | Mi ò ní ṣe eléyìí mọ́ láíláí! |
| Now | 1) Nísinsìnyí 2) Báyìí |
| We have to leave now! | 1) A ní láti kúrò nísinsìnyí! 2) A ní láti kúrò báyìí!! |
| Sometimes | Nígbà mìíràn |
| Sometimes I prefer to be at home | Mo fẹ́ láti wà ní ilé nígbà mìíràn |
| From time to time | Lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan |
| From time to time I eat Jollof rice | Mo ń jẹ ìrẹsì jọ̀lọ́ọ̀fù lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan |
| Late | Pẹ́ |
| The bus is always late | Ọkọ̀ èrò máa ń pẹ́ nígbà gbogbo |
| It is late | 1) Ó pẹ́ 2) Ó ti pẹ́ |
| Later | Nígbà míì |
| The bus will come later | Ọkọ̀ èrò máa ń wà nígbà míì |
| Early | Tètè |
| You should try to come home early | Ó yẹ kí o gbìyànjú láti tètè wá sí ilé |
