| What day is today? | Ọjọ́ wo ni òní bọ́ sí? |
| Monday | Ajé |
| Tuesday | Ìṣẹ́gun |
| Wednesday | Ọjọ́rú |
| Thursday | Ọjọ́bọ̀ |
| Friday | Ẹtì |
| Saturday | Àbámẹ́ta |
| Sunday | Àìkú |
| What day is today? | Ọjọ́ wo ni òní bọ́ sí? |
| Monday | Ajé |
| Tuesday | Ìṣẹ́gun |
| Wednesday | Ọjọ́rú |
| Thursday | Ọjọ́bọ̀ |
| Friday | Ẹtì |
| Saturday | Àbámẹ́ta |
| Sunday | Àìkú |
| This week | 1) Ọ̀sẹ̀ yìí 2) Lọ́sẹ̀ yìí |
| I have exams on Friday this week | Mo ní ìdánwò ní ọjọ́ ẹtì yìí |
| Next week | Ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀ |
| I will return next week Saturday | Mo máa padà ní ọjọ́ Àbámẹ́ta tó ń bọ̀ |
| Last week | Ọ̀sẹ̀ tó kọjá |
| He arrived from Ghana last week Monday | Ó dé láti ìlú Ghana ní ọjọ́ Ajé tó kọjá |
| I need to travel to Abuja on Monday because I have another flight on the same day that will arrive in Kenya on Tuesday | Mo ní láti lọ sí Àbújá ní ọjọ́ Ajé nítorí máa wọ ọkọ̀ òfuurufú mìíràn ní ọjọ́ kan náà tí yóò gbé mi dé ìlú Kenya ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun |
West Africa- Ìgbò - Wolof - Yorùbá |
East Africa- Chichewa (Nyanja) - Kinyarwanda (Ikinyarwanda) - Kiswahili |
Central Africa- Chokwe (Wuchokwe) - Ibinda (Fiote) - Kikongo - Lingala - Tshiluba |
Southern Africa- Malagasy - Naro (Senaro) - Nyaneka-Humbi - Sekaukau - Setswana (Tswana) - Shona (chiShona) - Umbundu (South Mbundu) - IsiXhosa (Xhosa) - IsiZulu (Zulu) |