Yorùbá Language


Talking about your family (Ebi) in Yorùbá

The Family Ẹbí
Mother 1) Ìyá
2) Màmá
Father Bàbá
Parents Òbí
Son 1) Ọmọ ọkùnrin
2) Ọmọkùnrin
Daugther 1) Ọmọ obinrin
2) Ọmọbinrin
Husband Ọkọ
Wife 1) Aya
2) Ìyàwó
Aunt Ẹ̀gbọ́n àgbà Obìnrin
Uncle 1) Ẹ̀gbọ́n àgbà Ọkùnrin
2) Bẹ́ẹ́rẹ̀
Grandmother 1) Ìyá ìyá
2) Ìyá màmá
3) Ìyá àgbà
Grandfather 1) Bàbá bàbá
2) Bàbá ìyá
3) Bàbá àgbà

How to talk about your family with examples in the plural case

My children Àwọn ọmọ mi
His parents Àwọn òbí rẹ
Your wives 1) Àwọn aya rẹ
2) Àwọn ìyàwó rẹ
The women here do not speak English 1) Àwọn obìnrin tí ó wà níbí kìí sọ èdè Gẹ̀ẹ́sì
2) Àwọn obìnrin tí ó wà níbí kìí sọ èdè Gẹ̀ẹ́sì

How to talk about your family with examples in the singular case

My wife is on the farm Ìyàwó mi wà ní inú ọkọ̀
Your husband speaks too much 1) Ọkọ rẹ máa ń sọ̀rọ̀ jù
2) Ọkọ̀ rẹ ń sọ̀rọ̀ púpọ̀
The uncle of the neighbour has a lot of girlfriends 1) ) Ẹ̀gbọ́n àgbà alábàágbé mi ní àwọn ọ̀rẹ́bìnrin púpọ̀
2) Bẹ́ẹ́rẹ̀ alábàágbé mi ní àwọn ọ̀rẹ́bìnrin púpọ̀
Our daughter is cooking Eba and Egusi 1) Ọmọ wa obìnrin ń tẹ Ẹ̀bà àti ọbẹ̀ Ẹ̀gúsí
2) Ọmọbìnrin wa ń tẹ Ẹ̀bà àti ọbẹ̀ Ẹ̀gúsí

Learn Yorùbá

------
African Languages on Mofeko

West Africa


- Ìgbò
- Wolof
- Yorùbá

East Africa


- Chichewa (Nyanja)
- Kinyarwanda (Ikinyarwanda)
- Kiswahili

Central Africa


- Chokwe (Wuchokwe)
- Ibinda (Fiote)
- Kikongo
- Lingala
- Tshiluba

Southern Africa


- Malagasy
- Naro (Senaro)
- Nyaneka-Humbi
- Sekaukau
- Setswana (Tswana)
- Shona (chiShona)
- Umbundu (South Mbundu)
- IsiXhosa (Xhosa)
- IsiZulu (Zulu)