Yorùbá Language


Yorùbá Numbers

1 Oókan
2 Eéjì
3 Ẹẹ́ta
4 Ẹẹ́rin
5 Aàrùn-ún
6 Ẹẹ́fà
7 Eéje
8 Ẹẹ́jọ
9 Ẹẹ́sàn-án
10 Ẹẹ́wàá
11 Ọ́kànlá
12 Eéjìlá
13 Ẹẹ́tàlá
14 Ẹẹ́rìnlá
15 Mẹ́ẹ̀ẹ́dógún
16 Mẹ́rìndínlógún
17 Mẹ́tàdínlógún
18 Méjìdínlógún
19 Mọ́kàndínlógún
20 Ogún

Yorùbá Numbers 30 - 100

30 Ọgbọ̀n
35 Aárùndínlógójì
40 Ogójì
45 Aárùndínláàádọ́ta
50 Àádọ́ta
55 Aárùndínlọ́gọ́ta
60 Ọgọ́ta
65 Aárùndínláàádọ́rin
70 Àádọ́rin
75 Aárùndínláàádọ́rin
80 Ọgọ́rin
85 Aárùndínláàádọ́rùn-ún
90 Àádọ́rùn-ún
95 Aárùndínlọ́gọ́rùn-ún
100 Ọgọ́rùn-ún

Yorùbá Numbers 200 - 1,000,000

200 Igba
1,000 Ẹgbẹ̀rùn-ún
10,000 Ẹgbẹ̀rùn-ún mẹ́wàá
100,000 ọ̀kẹ́ márùn-úǹkẹ́
One million Mílíọ́ọ̀nù kan

Learn Yorùbá

------
African Languages on Mofeko

West Africa


- Ìgbò
- Wolof
- Yorùbá

East Africa


- Chichewa (Nyanja)
- Kinyarwanda (Ikinyarwanda)
- Kiswahili

Central Africa


- Chokwe (Wuchokwe)
- Ibinda (Fiote)
- Kikongo
- Lingala
- Tshiluba

Southern Africa


- Malagasy
- Naro (Senaro)
- Nyaneka-Humbi
- Sekaukau
- Setswana (Tswana)
- Shona (chiShona)
- Umbundu (South Mbundu)
- IsiXhosa (Xhosa)
- IsiZulu (Zulu)