Yorùbá Language


How to greet and introduce yourself in Yorùbá

Welcome! 1) Káàbọ̀!
2) Ẹ* káàbọ̀! (e makes it formal)
Good Morning 1) Káàárọ̀
2) E káàárọ̀
Good Afternoon 1) Káàsán
2) Ẹ káàsán
Good Evening (early) 1) Kú Ìrọ̀lẹ́
2) Ẹ kú Ìrọ̀lẹ́
Good Evening 1) Káalẹ́
2) Ẹ káalẹ́
Good Night Ó dàárọ̀!
See you
--
See you later
Màá máa rí ẹ
--
Màá rí ẹ láìpẹ́
See you tomorrow Màá rí ẹ ní ọ̀la
Have a safe trip Wàá gúnlẹ̀ láyọ̀
Goodbye Ó dàbọ̀

So how can you introduce yourself?

What is your name? 1) Kín ni orúkọ ẹ?
2) Kín ni orúkọ yín?
My name is ____ Orúkọ mi ni ____
Where are you from? 1) Níbo ni ẹ ti wá?
2) Níbo ni o ti wá?
I am from ____ Mo wá láti Ìlú ____
Nice to meet you 1) Inú mi dùn láti pàdé ẹ
2) Inú mi dùn láti pàdé yín
How old are you? 1) Ọmọ ọdún mélòó ni ẹ́?
2) Ọmọ ọdún mélòó ni yín?
I am ____ years old Ọmọ ọdún ______ ni mí

How to check if someone is okay

How are you?
--
Whats up?
--
You good?
Báwo ni?
--
Kín ló ń ṣẹlẹ̀?
--
1) Ṣé dáadáa lo wà?
2) Ṣé dáadáa lẹ wà?
I'm okay
--
We are okay
Dáadáa ni mo wà
--
Dáadáa la wà
I'm great 1) Dáadáa ni mo wà
2) Mo wà ní àlàáfíà
I'm not good Mi ò wà dáadáa
--
Dáadáa kọ́ lo bá mi
I'm tired Ó ti rẹ̀ mí
I'm sick 1) Ara mi ò yá
2) Mo ń ṣàárẹ̀
I'm a bit sick 1) Mo ń ṣàìsàn díẹ̀
2) Àìsàn díẹ̀ ń ṣe mí

Learn Yorùbá

------
African Languages on Mofeko

West Africa


- Ìgbò
- Wolof
- Yorùbá

East Africa


- Chichewa (Nyanja)
- Kinyarwanda (Ikinyarwanda)
- Kiswahili

Central Africa


- Chokwe (Wuchokwe)
- Ibinda (Fiote)
- Kikongo
- Lingala
- Tshiluba

Southern Africa


- Malagasy
- Naro (Senaro)
- Nyaneka-Humbi
- Sekaukau
- Setswana (Tswana)
- Shona (chiShona)
- Umbundu (South Mbundu)
- IsiXhosa (Xhosa)
- IsiZulu (Zulu)