Yorùbá Language


Question Words in Yorùbá

Who? What? When? Where? Why? And How Much?

Here are some useful question words to help you ask the right questions with people in Yorùbá

Where? 1) Ibo
2) Nibo
Where is Seyi's house? Ibo ni ilé Sèyí wà?
Where is this? Ibo nibí yìí?
When? 1) Ìgbà wo?
2) Nígbà wo?
When is Rotimi coming? 1) Ìgbà wo ni Rótìmí ń bọ̀?
2) Ìgbà wo ni Rótìmí máa wá?
When will you travel? Ìgbà wo ni o máa rin ìrìn àjò?
How? Báwo?
How can I arrive to Ọ̀yọ́ State? Báwo ni mo ṣe lè dé Ìpínlè Ọ̀yọ́?
How can I get to Seyi's house? Báwo ni mo ṣe lè dé ilé Sèyí?
Which? Èwo?
Which of these men? Èwo nínú àwọn ọkùnrin yìí?
Which land is mine? Èwo ni ilé mi?
What? Kín ni?
What did you do? Kín ni o ṣe?
What did they tell you at the bank yesterday? Kín ni wọ́n sọ fún ẹ ní ilé ìfowópamọ́ lánàá?
Who? Ta ni?
Who is the traditional leader of this village? 1) Ta ni baálẹ̀ abúlé yìí?
2) Ta ni olórí abúlé yìí?
3) Ta ni ọba ìlú yìí?
Who did this? 1) Ta ni ó ṣe èyí?
2) Ta ló ṣe èyí? ?
Why? Ìdí?
Why did he do this? Kín ni ìdí tí o fi ṣe èyí?
Why is there no food Kín ni ìdí tí kò ṣe sí oúnjẹ?

How can you use "how much" to buy things?

How much? Eélòó?
How much is this food? Eélòó ni oúnjẹ yìí?
How much is a ticket to Abẹ́òkúta? Eélòó ni owó bàlúù lọ sí Abẹ́òkúta?

Learn Yorùbá

------
African Languages on Mofeko

West Africa


- Ìgbò
- Wolof
- Yorùbá

East Africa


- Chichewa (Nyanja)
- Kinyarwanda (Ikinyarwanda)
- Kiswahili

Central Africa


- Chokwe (Wuchokwe)
- Ibinda (Fiote)
- Kikongo
- Lingala
- Tshiluba

Southern Africa


- Malagasy
- Naro (Senaro)
- Nyaneka-Humbi
- Sekaukau
- Setswana (Tswana)
- Shona (chiShona)
- Umbundu (South Mbundu)
- IsiXhosa (Xhosa)
- IsiZulu (Zulu)